Mo binu si ore mi,
Mo so fun, irunu mi si tan.
Mo binu si ota mi,
Sugbon n o sofun, irunu mi si n dagba.
Mo bomirin pelu eru,
Ni asale ati owuru pelu omije oju:
Mo si n gbe pelu erin,
Ati pelu etan amunu dun mo eni.
On si n dagba ni osan ati loru,
Ti o si fi so eso elerin dodo apu.
Ota mi ri(eso na)to n tan,
O si mo daju wipe temi ni na.
O si yo kele wo nu ogba mi,
Nigba ti asale ti gbe opo mi.
Pelu inudidun ni mo fi ri lowuro;
Ota mi na tan labe igi(eso na) , o si ro.
(Written in Yoruba language)
A translation of the poem A Poison Tree by William Blake.