TIJANI ADEBOWALE DESTINY

Rookie - 47 Points (11,1,1990 / LAGOS; NIGERIA)

Anike - Poem by TIJANI ADEBOWALE DESTINY

Looto eranko bi kiniun sowon ninu igbo, otito sini wipe eja bi arogidigba sowon ninu odo.Nje omidan bi amolewa bi osupa, awelewa bi osumare tofi gbogbo ara se kikida ewa bi wura.Ibaje wipe gbogbo omidan lomo ibi ti otiri ewa tire, won ba malo ibe lo toro ewa, tabi wipe ewa re sefi owo ra.Anike, kikida eyin lo funfun balau to si n dan bi fadaka, ohun enu re amadun ni eti eni bi ti awon angeli, erin re asi mada eni lorun.Iru iyin wo ni aba yin eledumare to da omidan yii? iwa lewa, abefe, apon bepo re, oreke lewa, amo o loto gbogbo ibi ni won ti dana ale amo obe lodun ju irawon lo, loto opolopo omidan lowa, amoo omidan bi anike sowon larin awon elegbe re.ANIKE.Se ewa ni tire yii ni tabi osumare? tori wipe igbakugba ti n ba ti n wo ewa oju re, oma n je kinmo wipe kosi opin ninu owun ara ti eledumare da.Anike amolewa bi egbin, awelewa bi okin, abefe, atutu niwa bi adaba.Ti elomiran bama wi ani ewa re tan bi orun, elomiran ani rara o ewa re mole bi osupa, imiran asi fi ewa re we ti ododo.ANIKE.


Poet's Notes about The Poem

moko ewi yi fun eyin ju okan mi

Comments about Anike by TIJANI ADEBOWALE DESTINY

There is no comment submitted by members..Read this poem in other languages

This poem has not been translated into any other language yet.

I would like to translate this poem »

word flags

What do you think this poem is about?Poem Submitted: Friday, June 1, 2012

Poem Edited: Saturday, June 2, 2012


[Report Error]