Looto eranko bi kiniun sowon ninu igbo, otito sini wipe eja bi arogidigba sowon ninu odo.Nje omidan bi amolewa bi osupa, awelewa bi osumare tofi gbogbo ara se kikida ewa bi wura.Ibaje wipe gbogbo omidan lomo ibi ti otiri ewa tire, won ba malo ibe lo toro ewa, tabi wipe ewa re sefi owo
...
Read full text