Omo Aje Bota! Poem by G. Akanji Olaniyi

Omo Aje Bota!

Ewo omo aje bota
To n’look down si omo to jade ninu gota
O lohun ole ba jade lo sita
Nitori pe odabi omota
Ogbagbe pe aye pe meta
Igba ti aba ta
Igba ti ak
Ati igba ti kosi ohun ti a o ta
Tani omo ojo t’oja ota
Tabi ojo ti konita
Tabi owo ti a o se ta
Afi Olohun to da wa si aye meteta
Igba kolo bi orere pelu ohun ti a nta
Aye olo bi opa ibon ninu ohun ti a kota
Ori lo nise ninu ohun tita
Oba Oluwa aaje kamo igba oja nta
Tori omo to jade ninu gota
Ole di omo aje bota! ! !

Olaniyi G. Akanji
© 2015

COMMENTS OF THE POEM
READ THIS POEM IN OTHER LANGUAGES
Close
Error Success