Ti oluwa ni ile ati ekun re,
L'owo Re, Ona aye mi han gbangba.
Ni awon ojo ayo ati awon ojo Miran.
Mo gbekele Pe Oun yoo dari mi,
Pa mi mon ninu ewu oluwa.
Niwaju Re Mo ri alafia at‘ore ofe.
Ohun yowù bi àdanwo tàbi ipanju ti lè dé,
Mo moǹ pé ninu re ni agbara mi wa.
Mo fi gbogbo re fun O, Iberu ati iyemeji mi, Nitoripe ogbon Re koja gbogbo ironu temi.
Emi ni omo Re, eda Re, Ololufe Re.
Ati ninu itoju re, Mo ri alafia to peye.
Nitori ninu ife Re, Ireti mi ki y‘o din ku.
Olorun lo ni mi, ninu otito na ni mo ri isimi,
N‘tori niwaju Re L‘ododo ati'bukun mi gbe wa.
This poem has not been translated into any other language yet.
I would like to translate this poem