Oluwa! ! ! Mo nboju w'oke
Nitori wipe mofe g'oke
Wafi owo agbara re fami s'oke
Ki emi na le d'oke
Iwo ni oni gbogbo oke
Osi tun njoko si gbogbo aye ati s'oke
Wa gba aaye fun mi l'oke
Nitori aaye po gaan l'oke
Bi mo se ngun oke
Mase je ko nira fun mi lati d'oke
Nigba ti mo bawa d'oke
See ni irorun fun mi l'oke
Olaniyi G. Akanji
© 2015
This poem has not been translated into any other language yet.
I would like to translate this poem