Omode o mogun on pe le fo,
Sebi taba wi fun omo eni a gbo.
Sebi nitori aigboran omo rogun,
Lo se tori bo omi ogun.
Ijakadi a maa wa,
Sugbon suuru ni oba iwa.
Apata aye iba dide nitori ti re,
Nipa egbon tabi ore re.
Se iyen wa ni ko se lodi,
Si ofin olorun ati ti awon obi?
Put not judgement in your hand.
Rather, in your parent's law, fix a stand.
Oun ti agbalagba nri lori ijoko.
A juvenile can't see, even if he climb an iroko.
C.2017
This poem has not been translated into any other language yet.
I would like to translate this poem
Omode! Thanks for sharing this poem with us.
It's a pleasure sir